Gospel Tract and Bible Society

Ẹ káàbọ̀ sì ilé isẹ Gospel Tract and Bible Society. Ilépa Gospel Tract and Bible Society ni láti máa ṣe ìpín fún ní Ìròyìn Rere tí Ìgbàlà láti inú oore ọ̀fẹ́, nípa ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì, nípasẹ̀ èyí láti mú iṣẹ́ ìránṣẹ́ Krístì wá sí ìmúṣẹ.

Ẹ pé Wàá

Tí o bá ní àwọn ìbéèrè nípa Bíbélì tàbí ó nifẹ láti bá ẹlòmíràn sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìwé yìí, jọ̀wọ́ kọọ́ sì àwọn àlàfo inú ìwé tí ó wà ní ìsàlẹ̀ yìí. Ó sì tún lè béèrè fún àwọn ìwé ìléwọ́ wọ̀nyí lọ́fẹ̀ fún kíkà àti pípín fún àwọn ènìyàn, a ṣetán láti fi rànsẹ́ sí yín.


Béèrè fún àwọn ìwé ìléwọ́