Ìgbékalẹ̀ Lílò rẹ.

Lílo àti ìtún-fi rànsẹ́ àpilẹ̀kọ wọ̀nyí

Àwọn ìwé ìléwọ́ ìhìn-rere wá ní a gbé kalẹ̀ fún ìrọrùn yín. Wà ní òmìnira láti tẹ̀ẹ́ jáde kí o sì ló láti pín ìhìn rere fún ẹbí, àwọn ọ̀rẹ́ àti ojúlùmọ̀ gbogbo. A sì tún fún ọ ní àǹfààní láti fi rànsẹ́ sí àwọn ibòmíràn. Ṣùgbọ́n àwọn ohun tí a ń fẹ́ ni pé, kí o wá ní alaìyípadà sí bí a ti kọ wọ́n tẹ́lẹ̀. Kí ẹ sì ṣe ìtọ́kasí “Website” wa síbẹ̀.

Fi asöpọ̀(link) kún ojú awẹ́ ìwé (page) rẹ.

Da HTML kọ kí o sì lẹ díẹ̀ sára ojú awẹ́ ìwé (page) rẹ, kí ó sì pèsè àsopọ̀(link) mọ́ ọ̀rọ̀ inú ìwé yìí fún àwọn tí yóò lo wọ́n.

<a href="https://yor.gtbs.org">Tẹ ibí yìí láti ka àpilẹ̀kọ inú Bíbélì. </a>